
Tope Alabi Ba Eleda Laja Lyrics
[Verse 1]
Asan laye ati nkan gbogbo
To nwu libi i wura didan
Kole gbeni nu etan aye
Owo ofo la o pada lo
[Chorus]
Ki o towo iwo orun
Ki o tode Iwo osupa
Emi a beleda mi laja
[Verse 2]
Igba a lo bi agogo
Odo wa n sise e ewu
O nsun mowa eda ko kaakun
Se giri ero o nbo dede
[Verse 3]
Bi sun re bada ohun lomi
Baye bata ni afa o mora
Ife re ju tara atebi
Isun re dara yo sun aigbe
[Verse 4]
Tete ba eleda laja
Korun towo kosupa tode
Ko yi pada lona egbe
Olugbala lo npe o wa
[Chorus]
Ki o towo iwo orun
Ki o tode Iwo osupa
Emi a beleda mi laja
Written by; Tope Alabi
Released date; 9 November, 2020