
Tope Alabi Jesu Ore Otito Lyrics
[Verse 1]
Wa sodo re yio gba o
Oun nikan ni mole to tan so kunkun
Oro re iye, o n gba ni la
Ko tun sona miran tole gbani
[Chorus]
Jesu jesu ore otito
Jesu kristi iye loro re
Otan mole so kunkun u aye wa
Enito gba jesu loni iye.
[Verse 2]
Wa ma sonu, aye jin na
Oun nikan lole rin o sebute
Aye so kunkun, jesu ni mole
Gbagbo yio mu o debi isimi
[Verse 3]
Faye re fun, fokan re fun
Mase je kona re mo loju re
Oluwa n kan lekun, ore ma se aya
Ayo la o fi ba jesu joba
[Verse 4]
Oun adun ni keru wiwo di itan
Alafia ti aye kori ni
Ifokanbale irorun, eyi to logo
La jogun fawon toluwa gbala
Written by; Tope Alabi
Released date; 9 November, 2020